Àìsáyà 33:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ tí ó wà lọ́nà jínjìn, gbọ́ ohuntí mo ti ṣe;Ìwọ tí ò ń bẹ nítòsí, jẹ́rìí agbára mi!

Àìsáyà 33

Àìsáyà 33:4-19