Àìsáyà 31:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ní ọjọ́ náà, ẹnì kọ̀ọ̀kan yín yóò kọ àwọn ère fàdákà àti wúrà tí ọwọ́ ẹ̀ṣẹ̀ẹ yín ti ṣe.

Àìsáyà 31

Àìsáyà 31:6-9