Àìsáyà 30:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn màlúù àti àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tí ó ń tú ilẹ̀ yóò jẹ oúnjẹ àdídùn tí a fi amúga àti ṣọ́bìrì fọ́nkálẹ̀.

Àìsáyà 30

Àìsáyà 30:21-33