Àìsáyà 30:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Ègbé ni fún orílẹ̀-èdè alágídí náà,”ni Olúwa wí,“Fún àwọn tí ó gbé ètò jáde tí kì í ṣe tèmi,tí wọ́n ń gbìmọ̀ pọ̀, ṣùgbọ́n kì í ṣe nípa Ẹ̀mí mi,tí wọ́n ń dá ẹ̀ṣẹ̀ lórí ẹ̀ṣẹ̀;

2. tí wọ́n lọ sí Éjíbítìláì ṣe fún mi,tí ó ń wá ìrànlọ́wọ́ lọ́dọ̀ Fáráò fún ààbò,sí òjìji, Éjíbítì fún ibi ìsádi.

Àìsáyà 30