Àìsáyà 3:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn bodè Síònì yóò sunkún kíkorò, wọn ó ṣọ̀fọ̀,nítorí ó dahoro, yóò jókòó ní orí ilẹ̀.

Àìsáyà 3

Àìsáyà 3:20-26