Àìsáyà 3:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dípò òórùn dídùn, òórún búbubú ni yóò wá,okùn ni yóò wà dípò àmùrè,orí pípá ni yóò dípò ìrun ti a ṣe ní ọ̀ṣọ́aṣọ ọ̀fọ̀ ni yóò dípò aṣọ ẹ̀yẹ ìjóná dípò ẹwà.

Àìsáyà 3

Àìsáyà 3:15-26