Àìsáyà 27:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ní ọjọ́ náà, a ó fun fèrè ńlá kan. Gbogbo àwọn tí ń ṣègbé lọ ní Ásíríà àti àwọn tí ń ṣe àtìpó ní Éjíbítì yóò wá sin Olúwa ní òkè mímọ́ ní Jérúsálẹ́mù.

Àìsáyà 27

Àìsáyà 27:4-13