Àìsáyà 26:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọ àwọn tí ó ń gbé ní òkè di onírẹ̀lẹ̀ó rẹ ìlú agbéraga náà nílẹ̀;ó sọ ọ́ di ilẹ̀ pẹrẹṣẹó sì sọ ọ́ sílẹ̀ nínú erùpẹ̀.

Àìsáyà 26

Àìsáyà 26:1-14