Àìsáyà 26:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a fi oore-ọ̀fẹ́ hàn sí àwọn ìkàwọn kò kọ́ láti ṣòdodo;kódà ní ilẹ̀ àwọn tí ó dúró ṣinṣin wọ́ntẹ̀ṣíwájú láti máa ṣe ibiwọn kò sì ka ọlá ńlá Olúwa sí.

Àìsáyà 26

Àìsáyà 26:3-13