Àìsáyà 26:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ náà ni a ó kọ orin yìí ní ilẹ̀ Júdà:Àwa ní ìlú alágbára kan,Ọlọ́run fi ìgbàlà ṣeògiri àti ààbò rẹ̀.

Àìsáyà 26

Àìsáyà 26:1-7