Àìsáyà 25:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà àwọn ènìyàn alágbára yóòbọ̀wọ̀ fún ọ;àwọn ìlú orílẹ̀ èdè aláìláàánúyóò bọlá fún ọ.

Àìsáyà 25

Àìsáyà 25:1-12