Àìsáyà 22:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ mọ agbemi sí àárin ògiri méjìfún omi inú adágún àtijọ́,ṣùgbọ́n ìwọ kò wo ẹni tí ó ṣe é tẹ́lẹ̀tàbí kí o kọbi ara sí ẹni tí ógbérò rẹ̀ ní ìgbà pípẹ́ ṣẹ́yìn.

Àìsáyà 22

Àìsáyà 22:1-15