Àìsáyà 20:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni Áṣíríà yóò kó àwọn ìgbèkùn Éjíbítì lọ ní ìhòòhò àti láì wọ bàtà pẹ̀lú àwọn àtìpó Kúṣì, ọ̀dọ́ àti àgbà, pẹ̀lú ìbàdí goloto—bí àbùkù Éjíbítì.

Àìsáyà 20

Àìsáyà 20:1-6