Àìsáyà 2:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èyí ni ohun tí Àìsáyà ọmọ Ámósì rínípa Júdà àti Jérúsálẹ́mù:

2. Ní ìgbẹ̀yìn ọjọ́òkè tẹ́ḿpìlì Olúwani a ó fi ìdí rẹ̀ kalẹ̀gẹ́gẹ́ bí olú nínú àwọn òkè,a ó sì gbé e ga ju àwọn òkè kékeré lọ,gbogbo orílẹ̀ èdè yóò sì máa ṣàn sínú un rẹ̀.

3. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni yóò wá, wọn ó si sọ pé“Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á gòkè lọsí òkè Olúwa,sí ilé Ọlọ́run Jákọ́bù.Òun yóò kọ́ wa ní ọ̀nà rẹ̀,kí àwa kí ó lè rìn ní ọ̀nà rẹ̀.”Òfin yóò jáde láti Síhónì wá,àti ọ̀rọ̀ Olúwa láti Jérúsálẹ́mù wá.

Àìsáyà 2