Àìsáyà 19:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo omi inú odò ni yóò gbẹ,gbogbo ilẹ̀ odò ni yóò gbẹ tí yóò sì sáàpá.

Àìsáyà 19

Àìsáyà 19:1-11