Àìsáyà 19:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì jẹ́ ààmì àti ẹ̀rí sí Olúwa àwọn ọmọ-ogun ní ilẹ̀ Éjíbítì. Nígbà tí wọ́n bá ké pe Olúwa nítorí àwọn aninilára wọn, yóò rán olùgbàlà àti olùgbéjà kan sí wọn tí yóò sì gbà wọ́n sílẹ̀.

Àìsáyà 19

Àìsáyà 19:14-23