Àìsáyà 19:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi yóò rú àwọn ará Éjíbítì sókè sí ara wọnarákùnrin yóò bá arákùnrin rẹ̀ jà,aládúgbò yóò dìde sí aládúgbò rẹ̀,ìlú yóò dìde sí ìlú,ilẹ̀ ọba sí ilẹ̀ ọba.

Àìsáyà 19

Àìsáyà 19:1-10