Àìsáyà 19:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbo ni àwọn ọlọ́gbọ́n ènìyàn rẹ wà báyìí?Jẹ́ kí wọn fi hàn ọ́ kí wọn sì sọ ọ́ di mímọ̀ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogunti pinnu lórí Éjíbítì.

Àìsáyà 19

Àìsáyà 19:8-21