Àìsáyà 17:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìlú olódi ni yóò pòórá kúrò ní Éfáímù,àti agbára ọba kúrò ní Dámásíkù;àwọn àsẹ́ku Árámù yóò dágẹ́gẹ́ bí ògo ti àwọn Ísírẹ́lì,”ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.

Àìsáyà 17

Àìsáyà 17:1-9