Àìsáyà 17:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ ìmọ̀ tí ó kan Dámásíkù:“Kíyèsíí, Dámásíkù kò ní jẹ́ ìlú mọ́ṣùgbọ́n yóò padà di ààtàn.

Àìsáyà 17

Àìsáyà 17:1-5