Àìsáyà 15:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo omi Nímírímù ni ó ti gbẹàwọn koríko sì ti gbẹ,gbogbo ewéko ti tánewé tútù kankan kò sí mọ́.

Àìsáyà 15

Àìsáyà 15:5-9