Àìsáyà 15:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Díbónì gòkè lọ sí tẹ́ḿpìlìi rẹ̀,sí àwọn ibi gíga rẹ̀ láti ṣunkún,Móábù pohùnréré lórí Nébónì àti Médíbà.Gbogbo orí ni a fágbogbo irungbọ̀n ni a gé dànù.

Àìsáyà 15

Àìsáyà 15:1-4