Àìsáyà 14:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kígbe, Ìwọ ẹnu ọ̀nà! Pariwo, Ìwọ ìlú!Yọ́ kúrò, gbogbo ẹ̀yin Fílístínì!Kurukuru èéfín kan ti Àríwá wá,kò sì sí amóríbọ́ kan nínú ẹgbẹ́ wọn.

Àìsáyà 14

Àìsáyà 14:26-32