Àìsáyà 14:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn tí ó rí ọ yóò tẹjúmọ́ ọ,wọ́n ronú nípa àtubọ̀tán rẹ:“Ǹjẹ́ èyí ni ẹni tí ó mi ayé tìtìtí ó sì jẹ́ kí àwọn ilẹ̀ ọba wárìrì.

Àìsáyà 14

Àìsáyà 14:15-25