Àìsáyà 14:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò fi àánú hàn fún Jákọ́bù,yóò tún Ísírẹ́lì yàn lẹ́ẹ̀kan síiyóò sì fi ìdíi wọn kalẹ̀ ní ilẹ̀ àwọn tìkálára wọn.Àwọn àjèjì yóò darapọ̀ mọ́ wọn,wọn yóò sì fọwọ́ṣowọ́pọ̀ pẹ̀lú ilée Jákọ́bù.

Àìsáyà 14

Àìsáyà 14:1-11