Àìsáyà 13:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n wá láti ọ̀nà jínjìn réré,láti ìpẹ̀kun ọ̀run wá Olúwa pẹ̀lú àwọn ohun ìjà ìbínú un rẹ̀—láti pa gbogbo orílẹ̀ èdè náà run.

Àìsáyà 13

Àìsáyà 13:1-13