Àìsáyà 13:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bábílónì, ohun ọ̀ṣọ́ àwọn ìjọbaògo ìgbéraga àwọn ará Bábílónìni Ọlọ́run yóò dojúrẹ̀ bolẹ̀gẹ́gẹ́ bí Sódómù àti Gòmórà.

Àìsáyà 13

Àìsáyà 13:17-22