Àìsáyà 11:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kò ní ṣeni lọ́ṣẹ́ tàbí panirunní gbogbo òkè mímọ́ mi,nítorí gbogbo ayé yóò kún fún ìmọ̀ Olúwagẹ́gẹ́ bí omi ti í bo òkun.

Àìsáyà 11

Àìsáyà 11:1-12