Àìsáyà 11:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò sọ di gbígbéàyasí òkun Éjíbítì,pẹ̀lú atẹ́gùn gbígbóná ni yóò na ọwọ́ọ rẹ̀,kọjá lórí odò Éúfírétì.Òun yóò sì sọ ọ́ di ọmọdò méjetó fi jẹ́ pé àwọn ènìyànyóò máa là á kọjá pẹ̀lúu bàtà.

Àìsáyà 11

Àìsáyà 11:7-16