Àìsáyà 11:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Owú jíjẹ Éfáímù yóò pòórá,àwọn ọ̀tá Júdà ni a ó ké kúrò,Éfáímù kò ní jowúu Júdà,tàbí Júdà kó dojú kọ Éfáímù.

Àìsáyà 11

Àìsáyà 11:6-16