Àìsáyà 10:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò gé igbó dídí pẹ̀lú àáké,Lẹ́bánónì yóò ṣubú níwájú Alágbára náà.

Àìsáyà 10

Àìsáyà 10:32-34