2 Sámúẹ́lì 8:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóábù ọmọ Sérúyà ni ó sì ń ṣe olórí ogun; Jéhóṣáfátì ọmọ Áhílúdì sì ń ṣe akọ̀wé.

2 Sámúẹ́lì 8

2 Sámúẹ́lì 8:14-17