2 Sámúẹ́lì 23:33-35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

33. Ṣámà ará Hárárì,Áhíámù ọmọ Ṣárárì ará Hárárì;

34. Élífélétì ọmọ Áhásibáyì, ọmọ ará Máákíhà,Élíámù ọmọ Áhítófélì ará Gílónì;

35. Hésiráì ará Kérímélì,Páárì ará Áríbà;

2 Sámúẹ́lì 23