2 Sámúẹ́lì 23:25-28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

25. Ṣámà ará Háródì,Élíkà ará Háródì.

26. Hélésì ará Pálitì,Irá ọmọ Íkéṣì ará Tékóà;

27. Ábíésérì ará Ánétótì,Móbúnnáì Húṣátítì;

28. Sálímónì ará Áhóhì,Máháráì ará Nétófà;

2 Sámúẹ́lì 23