2 Sámúẹ́lì 22:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Olúwa sán án fún mi gẹ́gẹ́ bí òdodo mi;ó sì san án fún mi gẹ́gẹ́ bí mímọ́ ọwọ́ mi.

2 Sámúẹ́lì 22

2 Sámúẹ́lì 22:13-24