2 Sámúẹ́lì 19:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Méfíbóṣétì sì wí fún ọba pé, “Jẹ́ kí ó mú gbogbo rẹ̀, kí Olúwa mi ọba sáà ti padà bọ̀ wá ilé rẹ̀ ni àlàáfíà.”

2 Sámúẹ́lì 19

2 Sámúẹ́lì 19:29-38