2 Sámúẹ́lì 19:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. A sì rò fún Jóábù pe, “Wò ó, ọba ń sunkun, ó sì ń gbààwẹ̀ fún Ábúsálómù.”

2. Ìṣẹ́gun ijọ́ náà sì di ààwẹ̀ fún gbogbo àwọn ènìyàn náà, nítorí àwọn ènìyàn náà gbọ́ ní ijọ́ náà bí inú ọba ti bàjẹ́ nítorí ọmọ rẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 19