2 Sámúẹ́lì 18:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì wí fún un pé, “Yípadà kí o sì dúró nìhìn-ín.” Òun sì yípadà, ó sì dúró jẹ́ẹ́.

2 Sámúẹ́lì 18

2 Sámúẹ́lì 18:25-33