2 Sámúẹ́lì 17:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Húṣáì sì wí fún Sádókù àti fún Ábíátarì àwọn àlùfáà pé, “Bàyìí ni Áhítófélì ti bá Ábúsálómù àti àwọn àgbà Ísírẹ́lì dámọ̀ràn: báyìí lèmi sì báa dámọ̀ràn.

2 Sámúẹ́lì 17

2 Sámúẹ́lì 17:14-17