2 Sámúẹ́lì 17:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o bá sì bọ́ sí ìlú kan, gbogbo Ísírẹ́lì yóò mú okùn wá sí ìlú náà, àwa ó sì fà á lọ sí odo, títí a kì yóò fi rí òkúta kékeké kan níbẹ̀.”

2 Sámúẹ́lì 17

2 Sámúẹ́lì 17:12-15