2 Sámúẹ́lì 14:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì bí ọmọkùnrin mẹ́ta fún Ábúsálómù àti ọmọbìnrin kan ti orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Támárì: òun sì jẹ́ obìnrin tí ó lẹ́wà lójú.

2 Sámúẹ́lì 14

2 Sámúẹ́lì 14:19-33