2 Ọba 9:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéhù sọ wí pé, “Gbé e jùsílẹ̀ wọ́n sì jù ú sílẹ̀!” Díẹ̀ nínú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sì fọ́n sí ara ògiri àti àwọn ẹṣin bí wọ́n ti tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀ lábẹ́ ẹsẹ̀ wọn.

2 Ọba 9

2 Ọba 9:25-37