2 Ọba 7:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èlíṣà wí pé, “Gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa. Èyí ni ohun tí Olúwa sọ: Ní àsìkò yìí ní ọ̀la, a ó ta òṣùwọ̀n ìyẹ̀fun kíkúná kan ní ṣékélì kan àti méjì òṣùwọ̀n ọkà fún ṣékélì kan ní ẹnu bodè Samáríà.”

2. Ìjòyè kan ẹni tí ọwọ́ ọba ń fi ara tì dáhùn wí fún ènìyàn Ọlọ́run pé, “Ẹ wòó, tí Olúwa bá tilẹ̀ sí fèrèsé ọ̀run sílẹ̀, ṣé èyí lè rí bẹ́ẹ̀?”“Ìwọ yóò rí i pẹ̀lú ojú rẹ,” Èlíṣà dáhùn, “ṣùgbọ́n ìwọ kò ní jẹ nǹkankan lára rẹ̀!”

2 Ọba 7