2 Ọba 4:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n da ọbẹ̀ náà jáde fun àwọn ọkùnrin náà, ṣùgbọ́n bí wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ sí ní jẹ oúnjẹ náà, wọ́n sunkún jáde, “Ìwọ ènìyàn Ọlọ́run ikú ń bẹ nínú ìkòkò yìí!” Wọn kò sì le jẹẹ́.

2 Ọba 4

2 Ọba 4:35-41