2 Ọba 25:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gédálíà sì búrà láti fi dá àwọn ènìyàn rẹ̀ lójú. “Ẹ má ṣe bẹ̀rù àwọn ìjòyè ará káidéà,” ó wí pé, “Ẹ máa gbé ilẹ̀ náà kí ẹ sì sin ọba Bábílónì, yóò sì dára fún un yín.”

2 Ọba 25

2 Ọba 25:23-30