Hílíkíyà olórí àlùfáà sọ fún Ṣáfánì akọ̀wé pé, “Èmi rí ìwé òfin nílé Olúwa.” Ó fi fún Ṣáfánì, ẹni tí ó kà á.