2 Ọba 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì mú agbádá tí ó ti jábọ́ láti ọ̀dọ̀ Èlíjà ó sì padà lọ, ó sì dúró lórí bèbè Jọ́dánì.

2 Ọba 2

2 Ọba 2:11-17