2 Kíróníkà 6:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nígbà náà ni Sólómonì wí pé, “Olúwa ti sọ wí pé òun yóò máa gbé nínú ìkùku tí ó ṣú biribiri;

2. ṣùgbọ́n èmi ti kọ́ tẹ́ḿpìlì dáradára fún ọ ibi tí ìwọ yóò máa gbé títí láé.”

2 Kíróníkà 6