2 Kíróníkà 35:26-27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

26. Ìyòókù iṣẹ́ ìjọba Jósíà àti ìwà rere rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí èyí tí a ti kọ sínu ìwé òfin Olúwa.

27. Gbogbo iṣẹ́ náà, àti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin ni a kọ sínú ìwé àwọn ọba Ísírẹ́lì àti Júdà.

2 Kíróníkà 35