2 Kíróníkà 35:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti àjọ ìrékọjá a sì pa ẹran, àwọn àlùfáà sì wọ́n ẹ̀jẹ̀ náà tí wọ́n gbé sí ọwọ́ wọn, nígbà tí àwọn ọmọ Léfì sì bo ẹranko.

2 Kíróníkà 35

2 Kíróníkà 35:4-17